Aláàfin titun ti dé adé Sàngó;Ó gbàdúrà fún Nàìjíríà
Aláàfin ìlú ọ̀yọ́,Ọba Akeem Abímbólá Ọ̀wọ́adé ti rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà lápapọ̀ láti gba àlàáfíà láàyè ní ọ̀nà wọn gbogbo.
Nítorí Pé Wọ́n jí Pọ̀nmọ̀; Ilé-ẹjọ́ rán tọ̀mọ-tìyá lẹ́wọ̀n
Adájọ́ Odùmóṣù tí ilé ẹjọ́ Májísìréètì tó wà ní Àgọ́ Òkò ní Abẹ́òkúta ti fi kobíowú wọn ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́ta
Ẹ̀ṣìn Kristẹni kò pọn án ní dandan fún wa láti fẹ ìyàwó kan ṣoṣo…Ọjọ̀gbọ́n Alànà.
Ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ nípa májẹ̀mú titun ní ilé ẹkọ gíga julọ Yunifásítì Adékúnlé Ajáṣin tó wà ní Àkùngbá-Àkókó, Olú Alànà ti
Ìjọba Àpapọ̀ Kéde Ọjọ́ Kìíní àti Ìkejì Oṣù kẹrin gẹ́gẹ́ bíi Họludé ọ̀dún Ìtúnu Ààwẹ̀.
Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé nílẹ̀ wa,Olúbùnmi Túnjí Òjó ti kéde ọjọ́ ajé ọjọ́ kìíní àti ọjọ́ ìṣẹ́gun ọjọ́ keji oṣù
Adéwálé Àyúbà Pé ẹni Ọgọ́ta Ọdún láyé: Tinúbú kí i kú oríire
Èèkàn Olórin fújì nnì tíì tún ṣe ọba orin fújì Bọ̀ǹsúè ló ti pé ọgọ́ta ọdún lókè erùpẹ̀.Ogunlọ́gọ̀ àwọn ènìyàn
Ìtìjû Ńlá! Àwọn ènìyàn ẹkùn Ìdìbò Natasha fẹ́ fi ìbò Pè é Padà Wálé
Sẹ́nétọ̀ tó ń ṣojú ẹkùn ídìbò ààrin gbùngbùn Kogi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà,Sẹ́nétọ̀ Natasha Akpoti Uduaghan ló ṣeéṣe kó
Ó mà ṣe o!Wọ́n jí Àlùfáà Gbé ní Imo
Àwọn Ajínigbé ti gbé àlùfáà ìjọ Àgùdà kan ní Ejemekwuru, ni agbègbè ìjọba Ìbílẹ̀ Oguta, ní ìpínlẹ̀ Imo.Onitọ̀hún ni Àlùfáà
Kàyéfì Ńlá! Ẹni Àádọ́rin ọdún Ń ta Ẹ̀yà Ara Ènìyàn Ni Ìbàdàn
Ọwọ́ pálábá àwọn Amòòkùnsìkà ẹ̀dá tí wọn yan iṣẹ́ òkú wíwú àti ẹ̀yà ara ènìyàn títà láàyò ti ṣégi ní
Àkọ̀ròyìn Ilẹ̀ Ghana gba òbìtìbítí owó ìtanràn lórí ẹjọ́ ìbanilórúkọjẹ́ tó pe Olóṣèlú ilẹ̀ náà kan
Ògbóhùtarìgì akọ̀ròyìn tó máa ń fi irun bójú fín àwọn Amòòkùnsìkà lápe ní ilẹ̀ Ghana nnì,Anes Aremeyaw ni ilé ẹjọ́
