Okpebolor ni Edo dìbò fún, kìí ṣe Ighodalo… Ìgbìmọ̀
Ìgbìmọ̀ tó ń gbẹ́jọ́ awuyewuye tó ṣúyọ látàrí ètò ìdìbò sí ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Edo tó wáyé ní ọjọ́ kọkànlélógún
Ah! Ó mà ṣe o!Olówó fowó ra ikú;Alágbàṣe ṣá Ọ̀gá rẹ̀ pa ní Oko Oǹdó.
Gógó ni abúlé Láòṣò nítòsí Lájé ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Ìwọ̀ òòrùn Oǹdó kan níbẹ̀rẹ̀ ọ̀ṣẹ̀ yìí.Ohun tó mú ìkorò
Ojúṣe mi ni láti Sìn ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa… Andrew Ògúnṣakin
Alága ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa, Họnọrèbù Andrew Ògúnṣakin ti sọ pé ìdàgbàsókè ìjọba Ìbílẹ̀ Òkìtìpupa ló jẹ òun lógun.Ògúnṣakin ṣàlàyé ọ̀rọ̀
N ó rọ Ọba yòówù tí ìlú rẹ̀ bá tún jà lóyè ..Adélékè kìlọ̀ fún ifọ́n,Ìlobùú àti Ẹ̀rìn- Ọ̀ṣun.
Gómìnà Adémọ́lá Adélékè ti ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ti jáwé akìwọwọ fún àwọn ènìyàn Ifón,Ìlobùú àti Ẹ̀rìn-Ọ̀ṣun kí wọ́n ṣíwọ́ ogun àjàdijú
Ní ìpínlẹ̀ Kwara:Ìjì jà,ó lé ọba kúrò ní Ààfin,Ó já Mọsálásí àti Sọ́ọ̀sì sí ìhòhò
Òjò àrọ̀ìrọ̀dá kan tó ti lọ́jọ́ ọdún ìtúnu àwẹ̀ tó kọjá yìí ti sọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn dì aláìnílé lórí mọ
Nítorí ìlú tó le; Owó Oṣù Mẹ́rin ni mo jẹ àwọn Òṣìṣẹ́ Mejilélógójì (42) tí mo ní… Ibrahim Chatta
Gbajúgbajà òṣìṣẹ́ tíátà tó ní ẹ̀bùn àìmọye nnì, Ibrahim Chatta ti lahùn síta láìfòlò fọhùn pé lóòótọ́ ni ìlú le
