Òjòjò kò ṣe mí o.Koko lara mi le….Wike
Mínísítà fún olú ìlú ilẹ̀ wa, Nyensom Wike ti fèsì sí ọ̀rọ̀ kan tó ń jà ràn-ìn-ràn-ìn kiri pé ara […]
Mínísítà fún olú ìlú ilẹ̀ wa, Nyensom Wike ti fèsì sí ọ̀rọ̀ kan tó ń jà ràn-ìn-ràn-ìn kiri pé ara […]
Ìgbìmọ̀ tó ń gbẹ́jọ́ awuyewuye tó ṣúyọ látàrí ètò ìdìbò sí ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Edo tó wáyé ní ọjọ́ kọkànlélógún
Gógó ni abúlé Láòṣò nítòsí Lájé ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Ìwọ̀ òòrùn Oǹdó kan níbẹ̀rẹ̀ ọ̀ṣẹ̀ yìí.Ohun tó mú ìkorò
Alága ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa, Họnọrèbù Andrew Ògúnṣakin ti sọ pé ìdàgbàsókè ìjọba Ìbílẹ̀ Òkìtìpupa ló jẹ òun lógun.Ògúnṣakin ṣàlàyé ọ̀rọ̀
Gómìnà Adémọ́lá Adélékè ti ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ti jáwé akìwọwọ fún àwọn ènìyàn Ifón,Ìlobùú àti Ẹ̀rìn-Ọ̀ṣun kí wọ́n ṣíwọ́ ogun àjàdijú
Òjò àrọ̀ìrọ̀dá kan tó ti lọ́jọ́ ọdún ìtúnu àwẹ̀ tó kọjá yìí ti sọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn dì aláìnílé lórí mọ
Gbajúgbajà òṣìṣẹ́ tíátà tó ní ẹ̀bùn àìmọye nnì, Ibrahim Chatta ti lahùn síta láìfòlò fọhùn pé lóòótọ́ ni ìlú le