Ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́; Ìjà Ààlà ilẹ̀ gbẹ̀mí lẹ́nu ẹnìkan, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ló fara pa yánnayànna nígbà tí ilé mẹ́sàn-án jó gúdúgúdú
Ìjà ààlà ìlẹ̀ ti gbẹ̀mí ẹnìkan tí wọ́n sì tiná bọ odidi ilé mẹ́sàn-án ní Àágba ní ìjọba ìbílẹ̀ Sùúrùlérè […]
Ìjà ààlà ìlẹ̀ ti gbẹ̀mí ẹnìkan tí wọ́n sì tiná bọ odidi ilé mẹ́sàn-án ní Àágba ní ìjọba ìbílẹ̀ Sùúrùlérè […]
Làlúrí burúkú ló ṣẹlẹ̀ lálẹ́ ọjọ́ ìṣẹ́gun ọ̀sẹ̀ yìí ní Santo Domingo ní orílẹ̀-èdè Dominican níbi tí àjà ilé fàájì
Àwọn Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ ilé ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun tó wà ní ìlú Ìré ti ti ilé ìwé gíga náà pa.Ohun
Gómìnà ìpínlẹ̀ Benue,Caleb Muftwang ti fẹ̀ṣùn kan àwọn Fúlàní darandaran tí wọ́n ń pa àwọn ènìyàn ipinlẹ̀ rẹ̀ bí ẹni
……ìfẹ̀hónú hàn gbòdé ní Àkúrẹ́……Wọ́n gbé òkú àwọn tí wọ́n pa lọ sí ẹnu ọ̀nà ọọ́fíìsì Gómìnà Ìbànújẹ dórí àgbà
Ògbóhuntarìgì Olóṣèlú kan tó ti fìgbà kan rí jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asojú-ṣòfin , Họnọrèbù Nicholas Ukachukwu ló jáwé olúborí
Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party nílẹ̀ wa Nàìjíríà ti fẹ̀ṣùn kan Olùdíje fún ipò Ààrẹ lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú