Ọmọ ilé ìgbìmọ̀ Asojúṣòfin kan ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun;Wọlé Ọ̀kẹ́ ti fi ẹgbẹ́ Òṣèlú PDP sílẹ̀.
Ògbóhùntarìgì Olóṣèlú kan tó tún jẹ́ ìtalẹ̀mú nínú ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Họnọrèbù Wálé Ọ̀kẹ́ ti fi ẹgbẹ́ Òṣèlú
Nítorí ikú ọmọ ọmọ Ọmọ́gẹ̀; alága ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa fòfin de àwọn Sarin-sagolo(Scavengers) ní ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa
Alága ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa, Họnọrèbù Andrew Ògúnṣakin ti fòfin de àwọn Sarin-sagolo ti a mọ̀ sí Scavengers ní ìjọba ìbílẹ̀
Ní Òdìgbó;Pásítọ̀ fún Abirùn ọmọ Ọdún Mẹ́tàlàá lóyún
Kàyéfì ńlá ló jẹ́ fún àwọn ènìyàn ìlú Òkè Ìgbúròwò ní ìjọba ìbílẹ̀ Òdìgbò nígbà tí àríyànjiyàn sọ lórí ẹni
Tìlùtìfọn ni àwọn ará Arárọ̀mí Seaside fi kí Aiyédàtiwa àtaya rẹ̀ káàbọ̀ síbi ayẹyẹ àjọ̀dún Àjíǹde
Kò ní yẹni títí kí ilẹ̀ má ṣe ṣú.Bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀ rí fún gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó, Lucky Orímisàn Aiyédàtiwa
Ní ìpínlẹ̀ Delta, Ọkọ Shimite Wilfred Bello tíì ṣe Amúgbalẹ́gbẹ̀ẹ Gómìnà ti lù ú pa.
Olùrànlọ́wọ́ pàtàkì fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Delta Sheriff Oborevwori lórí ọ̀rọ̀ òkòwò àti ọjà tó ń lọ sílẹ̀ òkèèrè Arábìnrin Shimite
Portable fi ẹ̀ṣẹ́ kán ọwọ́ Darlington:Burna Boy fún un ní Ogún Mílíọ̀nù Náírà.
Olórin ṣèwọ́ṣèwọ́ ọmọ Naijiria tó gba àmì ẹ̀yẹ Grammy nnì,Burna Boy ló tí fún Portable olórin ní ogún mílíọ̀nù náírà
Ní ilẹ̀ Amẹ́ríkà, ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ àwọn ènìyàn ṣe ìwọ́de tako ìjọba Donald Trump.Wọ́n ní ìjọba rẹ̀ ń ni àwọn lára
Ilẹ̀ Amẹrika ti sọ̀rọ̀ sókè tako gbogbo ìgbésẹ̀ ìjọba Donald Trump nípa síse ìwọ́de lọ́kan-ò-jọ̀kan káàkiri orílẹ̀-èdè náà.Wọ́n ní kò
