Ikú dóró! ìyàwó Gómìnà Akwa ibom tẹ́rí gbasọ.
Hmmm! Ikú ti gbẹ̀mí ìyàwó Gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, Arábìnrin Patience Umo Eno.Àná ọjọ́ ọjóbọ ni Arábìnrin ọ̀hún jẹ́ ìpè
Ìjọba Ìbílẹ̀ Méjìdínlógún ni ìdìbò yóò ti wáyé ní ìpínlẹ̀ Oǹdó….ODIEC
Àjọ eleto idibo nipinle Ondo tí a mọ̀ sí ODIEC ti bèrè itanijí ohun ìlánilọ́yẹ̀ fún àwọn olóṣèlú ní ìgbáradì
Ojora ti Mú Àwọn Mínísítà: Tinubu fẹ́ Tú Wọn ká
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú àwọn Mínísítà ìjọba àpapọ̀ ni jìnnìjìnnì ti mú nitori ìròyìn tó ń tàn kiri pe Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú
Edo 2024:Ajọ INEC gbìyànjú…. Joshua
Olùkọ́ àgbà Yunifásítì kan, tíí tún ṣe Olórí ẹ̀ka tó ń kọ́ni ní ìmọ̀ nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú nílé ẹ̀kọ́ gíga
Edo 2024:Okpebolo di Gómìnà
Àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Edo ti dìbò yan Gómìnà tuntun ti yóò máa ṣe àkóṣo ipinle náà fún ọdún mẹ́rin miiran.Onítọ̀hún
Ẹ fi Yahaya Bello sílẹ̀ o!Àwa la lowó tó kó jẹ…. Awọn Obìnrin Kogi
Bámúbámú ni gbogbo ọ̀nà igboro ìlú Lokoja kún fún àwọn olùfẹ̀hónú hàn tí gbogbo wọn gbé pátákó Ajúwe tó ń
Edo 2024: Oshiomole fẹ̀yìn Obaseki bẹ́lẹ̀
Bí-ó- tilẹ̀-jẹ́-pé àjọ INEC kò tíì sọ ẹni tó wọlé yanya ninu ètò ìdìbò sí ipò Gómìnà ìpínlẹ̀ Edo, ṣùgbọ́n
