Ìjọba Àpapọ̀ ti ṣetán láti san Àjẹ́ẹ́lẹ̀ owó sọ̀gbàdẹ̀rọ̀ fún Àwọn Òṣìṣẹ́ Rẹ̀
Ìjọba Àpapọ̀ ti ṣetán báyìí láti san Àjẹ́ẹ́lẹ̀ owó sọ̀gbàdẹ̀rọ̀ oṣù márùn-ún tó jẹ àwọn Òṣìṣẹ́ rẹ̀ yíká orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ọmọ Ẹgbẹ́ NULGE ní ìpínlẹ̀ Oǹdó wú mi Lórí…Akínrìnlọ́lá
Ààrẹ ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Oǹdó ti a mọ̀ sí NULGE,Comrade Frederick Gbénga Akínrìnlọ́lá ti lu àwọn
Ọkọ̀ Pa Ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ènìyàn níbi Ọdún Ìbílẹ̀ kan ni Vancouver Fillipino
Lójijì ni ìdùnnú òhun ayọ̀ sáré di ìbànújẹ níbi ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ kan ni Vancouver Fillipino lálẹ́ àná Sátidé nígbà
Ìjọba Nàìjíríà yóò sinmi ẹ̀yáwó láti ilé òkèèrè…. Wálé Ẹdun
Mínísítà fún ìsúná àti Alàkóso ètò ọrọ̀ ajé ní ilẹ̀ wa Nàìjíríà, Ọ̀gbẹ́ni Wálé Ẹdun ti sàlàyé pé ilẹ̀ wa
Àgbàlagbà ni Ifeanyi Okowa àti Sheriff Oborevwori ,Wọ́n lẹ́tọ̀ọ́ lábẹ́ òfin láti dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ tó bá wù wọ́n…. Atiku
Ìgbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú PDP láàrin ọdún 1999 sí ọdún 2027, tíì tún ṣe olùdíje sí
Kò ṣéèwọ̀ nínú kíkí tí Mo lọ Kí Buhari…Atiku
Ìgbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí tii tún ṣe olùdíje sí ipò Ààrẹ lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú PDP nínú ètò
Pope Francis yóò wọ káà ilẹ̀ sùn lónìí….. Vatican
Pápà mímọ́ jùlọ ti ìjọ Àgùdà lágbàáyé,Pápà Francis yóò wọ káà ilẹ̀ sùn lónìí. Ìròyìn tó tẹ̀ wá lọ́wọ́ láti
Abẹ́ Wá Lẹ wà,Ẹ ò ní Òmìnira:Fásúà kìlọ̀ fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Ìdàgbàsókè Agbègbè (LCDA)
Alága àwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Oǹdó, Họnọrébù Gbénga Fáṣúà ti kìlọ̀ fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ìdàgbàsókè agbègbè

