Ọkùnrin takuntakun ni Bathaza Ebang Egonga…Olólùfẹ́ Eré ìdárayá
Kò jẹ́ tuntun mọ́ pé Ọkùnrin olókó kòmẹbí kan ní ilẹ̀ Equitorial Guinea, Bathaza Ebang Egonga bá irínwó obìnrin lò […]
Kò jẹ́ tuntun mọ́ pé Ọkùnrin olókó kòmẹbí kan ní ilẹ̀ Equitorial Guinea, Bathaza Ebang Egonga bá irínwó obìnrin lò […]
Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó tó tún ṣẹ̀ṣẹ̀ jàwé Olúborí nínú ìdìbò sí ipò Gómìnà tó wáyé ni ìpínlẹ̀ Oǹdó lọ́jọ́ kẹtàdinlogun
Igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó,Ọláyídé Adélàmí ti jẹ́wọ́ ọmọ ọkọ ní yúníìtì ibi tó ti dìbò ní bó ti fẹ̀yìn olùdíje
Igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó,Ọláyídé Adélàmí ti pàrọwà fún àwọn ènìyàn ipinlẹ̀ Oǹdó lápapọ̀ pàápàá jùlọ àwọn ènìyàn Ọ̀wọ̀ ati agbègbè
Láròtẹ́lẹ̀ ni mọ́tò já okùn ẹ̀mí ọkùnrin Ọlọ́kadà kan ti orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Fàtáì ní Ìlú Bọ́lọ́rundúró tíì ṣe
Ìrìnàjò ìkẹyìn fún Diákónì Samson Òláníyì Adébáyọ̀ George ti bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ìṣìn ninu ijọ Oore-ọ̀fẹ́ Baptist Church, Ilẹ̀-Olújìí lánà-án Sunday.
Àlùfáà ìjọ Oore-ọ̀fẹ́ Baptist church,Ilẹ̀-Olújìí , Àlùfáà Philip Adékúnlé Ọmọ́kanyè ti rọ gbogbo ẹ̀dá alààyè láti máa ṣe àánú fún