Nítorí ikú tó Pa Ọlọ́pàá Blessing Yusuf: Àwọn Ọ̀dọ́ Na Ọ̀gá Ọlọ́pàá Ní Àlùpamópòó.
Bí àwọn ọlọ́pàá tó gbé òkú ọ̀kan lára wọn, Blessing Yusuf Suleiman tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ọmọ Alhaja lọ […]
Bí àwọn ọlọ́pàá tó gbé òkú ọ̀kan lára wọn, Blessing Yusuf Suleiman tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ọmọ Alhaja lọ […]
Kò dín ní ọmọ ilé Kéú Mẹ́tàdínlógún tó jẹ́ Ọlọ́run nípè láìròtẹ́lẹ̀ nínú ìjàm̀bá iná tó sọ ilé ẹ̀kọ́ kéú
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn,Dàpọ̀ Abíọ́dún ti pàṣẹ kí Olórílé ti Orílé-Ifọ̀ ní ìjọba ìbílẹ̀ Ifọ̀ ní ìpínlẹ̀ ògùn,Ọba Sẹ̀míù Ògúnjọbí pé
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun láàrin ọdún 1999 sí Ọdún 2003, tó ti tún fìgbà kan jẹ́ alága àkọ́kọ́ fún ẹgbẹ́ òṣèlú
ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ipinlẹ Enugu ti fi páḿpẹ́ òfin gbé òjòwúkùnrin kan Sunday Echege ,ẹni ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n tó ń gbé
Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó, Lucky Orímisàn Aiyédàtiwa ti sọ yanya pé ó di ọjọ́ kẹwàá oṣù kejì ọdún yìí kí wọ́n