Alága di Méjì ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, ọ̀kan ń ṣe ilé,Ìkejì Ń Ṣe ìjọba.
Lẹ́yìn ìdìbò sí ìjọba ìbílẹ̀ yíká ipinlẹ Ọ̀ṣun tó wáyé ní ọjọ́ Sátidé ọjọ́ kejìlélógún oṣù kejì ọdún yìí níbi […]
Lẹ́yìn ìdìbò sí ìjọba ìbílẹ̀ yíká ipinlẹ Ọ̀ṣun tó wáyé ní ọjọ́ Sátidé ọjọ́ kejìlélógún oṣù kejì ọdún yìí níbi […]
Irọ́ funfun báláú ni àhesọ ọ̀rọ̀ kántankàntan tí àwọn Aláìnífun nínú ẹ̀dá tí wọ́n jìnnà sí làákàyè bíi sánmà jìnnà
Kannakánná tó ń na ọmọ ẹ̀gà láàrin ìyàwó gómìnà ànà ní ìpínlẹ̀ Oǹdó,Betty Akérédolú àti Kọmísánnà fún ètò ìsúná Abilékọ
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ awuyewuye ló ti ń wáyé l’órí bí aya Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó kò ti sí ní ilé ìjọba.Kóda, nígbà tí
Olórí káààfàtà fún ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re,Bàbá àgbà Reuben Fáṣọ̀ràntì ti ṣàpèjúwe olóògbé Samuel Ayọ̀dèjì Adébánjọ gégé bíi ọlọ́pọlọ pípé,àgbà óṣèlú àti
Olórí ẹ̀ka kan nínú Ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re, Àlà gbà Ayọ̀ Adébánjọ ti di olóògbé.Kùtùkùtù Òwúrọ̀ òní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù Kejì ọdún
Abilékọ ẹni ọdún mẹ́rìnlèlógún kan, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Racheal tó fi ìlú Asaba ní ìpínlẹ̀ Delta ṣe ibùjókòó
Bíi fíìmù orí ìtàgé ló jọ nígbà tí àwọn Ajínigbé fi ọwọ́ taari ìpàkọ́ lèmọ́mù àti àwọn mẹ́sàn-án mìíràn sí