Ní ilẹ̀ Namibia, Obìnrin ni wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bíi Ààrẹ
Ilẹ̀ Namibia ti yan Ààrẹ àkọ́kọ́ lóbìnrin.Onítọ̀hún ni Abilékọ Netumbo Nandi Ndaitwah tí àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ mọ̀ sí NNN.Ọmọ ẹgbẹ́ […]
Ilẹ̀ Namibia ti yan Ààrẹ àkọ́kọ́ lóbìnrin.Onítọ̀hún ni Abilékọ Netumbo Nandi Ndaitwah tí àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ mọ̀ sí NNN.Ọmọ ẹgbẹ́ […]
Ọ ní òun kò jẹ̀bi ẹ̀ṣùn ìgbésùnmọ̀mí… Agbẹjọ́rò tuntun ,Kanu Agabi ló ń gbẹnusọ fún un báyìí.. Adájọ́ Binta iyako
Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà,Bọ́lá Tinúbú ti yan Ọ̀gàgún fẹ̀hìntì ojú omi Ibok Ette Ibas gẹ́gẹ́ bíi Alákòóso ìjọba ìpínlẹ̀ Rivers. Eléyìí
Nítorí rúkèrúdò òṣèlú tó tí ń mi ìpínlẹ̀ Rivers lògbòlògbò fún ìgbà pípẹ́ láàrin Gómìnà Siminalaye Fubara àti bàbá-ń-gbẹ̀jọ́ rẹ̀
Ògbóhùntarìgì Afèdèsẹṣọ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ nnì, tí àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ mọ̀ si Kẹ̀kẹ́àwàdà, Ọ̀gbẹ́ni Adékúnlé Adéwùmí tíí ṣe Olùdarí ilé iṣẹ́ kẹké Àwàdà
Láti inú oṣù Kejì tí òjòjò ti ń ṣògún Pápà mímọ́ jùlọ Fransisco ti ìjọ Àgùdà lágbàáyé,ọọ́fíìsì Alukoro àgbà fún
Bí ẹ̀ṣùn tí ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Rivers fi kan Adájọ́ àgbà ní ìpínlẹ̀ náà pé ó yí ọjọ́ oríire rẹ̀
Ẹgbẹ́ Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní Nàìjíríà tí a mọ̀ sí ANBROAD, ẹ̀ka ti ìpínlẹ̀ Oǹdó ti ṣí ọọ́fíìsì titun.Ojúlé Kẹrìnléláàádọ́ta, agbègbè