Ó mà ṣe o!Tukana Di olóògbé

Àkọ̀wé ijọba ìpínlẹ̀ Oǹdó, Ọ̀gbẹ́ni Táyọ̀ Olúwatúyì tí gbogbo àwọn ènìyàn mọ̀ sí Tùkànà ló ti di olóògbé.

Òwúrọ̀ òní ló dákẹ́ ní ilé ìwòsan kan ní ìlú Àkúrẹ́.Ọdún tó kọjá ní Tùkànà ṣe èṣe nínú ìjàm̀bá mọto kan.Láti ìgbà náà ló ti wá lórí àketè kí ikú tó gba èmi rẹ ní òwúrọ̀ òní.

Kí Olúwa ti ẹ sí afẹ́fẹ́ rere.

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top
×