
Ìjọba ìpínlẹ̀ Oǹdó ti ṣe àmúṣẹ ìlérí rẹ láti ríi dájú pé ayé túbọ̀ dẹndẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ ijoba ipinle náà nipa sisan owó oṣù tuntun eleyii tí ìjọba Àpapọ̀ ilẹ Naijiria fọwọ́ sí lẹ́nu lọ́ọ́lọ́ọ́ yìí.
Àná ni Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó,Lucky Orímisàn Aiyédàtiwa fojú ọ̀rọ̀ yìí léde níbi tí wọ́n ti wón ti sí aṣọ lójú ipolongo ìbò Gómìnà ní ẹkùn ìdìbò Ààrin-gbùngbùn ìpínlè Ondó tí ó wáyé ni Pápá ìseré tó wa n ìlú Oǹdó .
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn ń bọ̀ láìpé .

Oyè Oyèdọ̀tun jẹ́ gbajúgbajà Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Oníròyìn,Akéwì,Olórin,Ọ̀ǹkọ̀wé, àti Ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn.Ìfẹ́ rẹ̀ sí iṣẹ́ ìròyìn àti èdè Yorùbá ló fa ìdásílẹ̀ ìkànnì yìí.A ti fi ìkòkò ṣe ọbẹ̀,ó yá ẹ je ká tọ́ ọ wò..Oyinmọmọ!
