Ìròyìn Ní Yàjóyàjó! Tinúbú kéde Ìjọba Pàjáwìrì Ní ìpínlẹ̀ Rivers

Nítorí rúkèrúdò òṣèlú tó tí ń mi ìpínlẹ̀ Rivers lògbòlògbò fún ìgbà pípẹ́ láàrin Gómìnà Siminalaye Fubara àti bàbá-ń-gbẹ̀jọ́ rẹ̀ tíì tún ṣe Mínísítà fún olú ìlú ilésà wa,Nyensom Wike, Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú ti kéde Ìjọba Pàjáwìrì ni ìpínlè Rivers.

Nínú ọ̀rọ̀ tó bá gbogbo ọmọ Naijiria sọ láagó méjè ìrọ̀lẹ́ yìí lórí ẹrọ Tẹlifísàn àti Rédíò ló ti pàṣẹ ìjọba Pàjáwìrì náà.

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn ń bá lọ́nà..

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top
×