ÌRÒYÌN NÍ YÀJÓYÀJÓ: AIYÉDÀTIWA GBÉ PDP LULẸ̀ L’Ọ́WỌ̀

Igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó,Ọláyídé Adélàmí ti jẹ́wọ́ ọmọ ọkọ ní yúníìtì ibi tó ti dìbò ní bó ti fẹ̀yìn olùdíje lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú PDP lélẹ̀ pẹ̀lú ìbò tó lé ní igba sí mọ́kànlàá péré.

Adélàmí tó dìbò ní agogo mẹ́wàá òwúrò kù dírẹ̀ ní Igboroko 2,Wọ́ọ̀dù keta yúníìtì kerindinlogun ní ìlú Ọ̀wọ̀ jáwé Olúborí nígbà tí wón ka ìbò náà tán tí àwọn Òṣìṣẹ́ INEC sì kéde ẹgbẹ́ òṣèlú APC gẹ́gẹ́ bíi ẹgbẹ tó gbé igbá orókè.

A ó máa fi àwọn èsì ìbò náà tó yín létí bí àjọ INEC, bá ti ń fi léde.

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top
×