Gómìnà ìpínlẹ̀ Sòkòtò Pín owó iléyá fún àwọn èrò Hajj

Gómìnà ìpínlẹ̀ Sòkòtò, Aliu Bamako ti Pin owó tó tó ẹgbẹ̀rún kan Riyad tí se owó ilé Saudi ti isiro rẹ to Ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọ̀tàlérinwó ó dín mẹ́wàá fún ìkọ̀ọ̀kan awon ero mékà tó wá láti ìpínlẹ̀ náà.

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top
×