
Ìyàwó àṣẹ̀ṣẹ̀gbé kan tí wọn kò tíì fi orúkọ rẹ̀ léde wà nibi tó ti ń ṣẹ́jú pàkò ní akóló àjọ ọlọ́pàá ipinlẹ Zamfara bayii lori èṣùn pé fi Májèlé Sínú Oúnjẹ àwọn àlejò tó wá sí ibi patí ìgbéyàwó wọn.Kódà,ẹlẹ́kọ ọ̀run polówó fún ọ̀kan lára àwọn àlejò ọ̀hún tí ọkọ ìyàwó fúnra rẹ̀ si wá ní ẹsẹ̀ kan ayé,ẹsẹ̀ kan ọ̀run.
Alukoro àjọ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ naa,Saii’lsu Adam ló fi ojú ọ̀rọ̀ yìí léde ní ìlú Guzau nígbà tó ń bá àwọn oníròyìn fọ̀rọ̀ jẹ̀wọ̀.
Adam ni ìyàwó àti àwọn ẹlẹ́gbẹ́rò rẹ̀ ni wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ láti ṣe ṣûtá náà.Ó wá tẹ̀ síwájú pé àjọ Ọlọ́pàá kò ní ainm

Oyè Oyèdọ̀tun jẹ́ gbajúgbajà Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Oníròyìn,Akéwì,Olórin,Ọ̀ǹkọ̀wé, àti Ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn.Ìfẹ́ rẹ̀ sí iṣẹ́ ìròyìn àti èdè Yorùbá ló fa ìdásílẹ̀ ìkànnì yìí.A ti fi ìkòkò ṣe ọbẹ̀,ó yá ẹ je ká tọ́ ọ wò..Oyinmọmọ!
