Ẹ bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò lórí Owó oṣù tuntun fún Àwọn Òṣìṣẹ́….Àjọ Àwọn Òṣìṣẹ́

Àjọ àwọn òṣìṣẹ́ nilẹ̀ wa ti ṣín àjọ tó ń bá ìjọba ìpínlẹ̀ kọ̀ọ̀kan jíròrò lórí owó oṣù tuntun ní gbẹ́rẹ́ ìpàkọ́ láti tètè Jáwé sóbì ìjíròrò wọn lẹ́yẹòṣọkà.

Àtẹ̀jáde kan láti olú ilé iṣẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ ló kéde òrò náà.

Gẹ́gẹ́ bí ó ṣe wà nínú àtẹ̀jáde náà,ìgbónágbooru làá jẹ opọ̀lọ́ ní kí wọn fi ọ̀rọ̀ náà ṣe nítorí bí ọ̀rọ̀ bá ti ń ọ nílẹ̀,ó máa ń gbọ́n ni

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top
×