Babańgbẹ̀jọ́ọ mi ló fún mí ní Mílíọ̀nù Marun-un Náírà (₦5m) Kí n fún Agbẹjọ́ròàgbà láti bá mi ra Àforíjìn…Bobrisky
Idris Olarewaju Okuneye tí a mọ̀ sí Bobrisky ti sàlàyé pé Babańgbẹ̀jọ́ọ òun ló bá òun san owó tó tó […]
Idris Olarewaju Okuneye tí a mọ̀ sí Bobrisky ti sàlàyé pé Babańgbẹ̀jọ́ọ òun ló bá òun san owó tó tó […]
Olórí ìjọ Ìràpadà Ọlọ́run lágbàáyé,(The Redeemed Christiana Church of God)Pásítọ̀ Adéjàre Adébóyè ti sọ lọ́jọ́ ẹtì tó kọjá lọ pé
Ọ̀kánjúwà ń dàgbà,ọgbọ́n ń rewájú, ilé iṣẹ́ imọ̀ ẹ̀rọ tó gbajumo nílẹ̀ Japan ti a mọ̀ sí Sanyo ti gbé
Ọ̀gá Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Oǹdó,Àbáyọ̀mí Peter Ọ̀ládipúpọ̀ ti rọ àwọn ọ̀gá ọlọ́pàá tí wọ́n sẹ̀sẹ̀ gba ìgbéga ní ìpínlẹ̀ náà kí
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú àwọn Mínísítà ìjọba àpapọ̀ ni jìnnìjìnnì ti mú nitori ìròyìn tó ń tàn kiri pe Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú
Bámúbámú ni gbogbo ọ̀nà igboro ìlú Lokoja kún fún àwọn olùfẹ̀hónú hàn tí gbogbo wọn gbé pátákó Ajúwe tó ń
Bí-ó- tilẹ̀-jẹ́-pé àjọ INEC kò tíì sọ ẹni tó wọlé yanya ninu ètò ìdìbò sí ipò Gómìnà ìpínlẹ̀ Edo, ṣùgbọ́n
Gómìnà ìpínlẹ̀ Edo, Godwin Obaseki ti sọ yanya ni ìlú Benin tii ṣe olúìlú ìpínlẹ̀ náà pé ibí yòówù tí
Itan Naijanotes.net Naijanotes.net jẹ ipilẹ ọgbọn kan ti a ṣe apẹrẹ lati mu awọn akoonu ti o yẹ jọ fun