Nítorí Pé Wọ́n jí Pọ̀nmọ̀; Ilé-ẹjọ́ rán tọ̀mọ-tìyá lẹ́wọ̀n
Adájọ́ Odùmóṣù tí ilé ẹjọ́ Májísìréètì tó wà ní Àgọ́ Òkò ní Abẹ́òkúta ti fi kobíowú wọn ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́ta […]
Adájọ́ Odùmóṣù tí ilé ẹjọ́ Májísìréètì tó wà ní Àgọ́ Òkò ní Abẹ́òkúta ti fi kobíowú wọn ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́ta […]
Ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ nípa májẹ̀mú titun ní ilé ẹkọ gíga julọ Yunifásítì Adékúnlé Ajáṣin tó wà ní Àkùngbá-Àkókó, Olú Alànà ti
Ọwọ́ pálábá àwọn Amòòkùnsìkà ẹ̀dá tí wọn yan iṣẹ́ òkú wíwú àti ẹ̀yà ara ènìyàn títà láàyò ti ṣégi ní
Ògbóhùtarìgì akọ̀ròyìn tó máa ń fi irun bójú fín àwọn Amòòkùnsìkà lápe ní ilẹ̀ Ghana nnì,Anes Aremeyaw ni ilé ẹjọ́
Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà,Bọ́lá Tinúbú ti yan Ọ̀gàgún fẹ̀hìntì ojú omi Ibok Ette Ibas gẹ́gẹ́ bíi Alákòóso ìjọba ìpínlẹ̀ Rivers. Eléyìí
Olórí ẹ̀ka kan nínú Ẹgbẹ́ Afẹ́nifẹ́re, Àlà gbà Ayọ̀ Adébánjọ ti di olóògbé.Kùtùkùtù Òwúrọ̀ òní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù Kejì ọdún
Àkọ̀wé ijọba ìpínlẹ̀ Oǹdó, Ọ̀gbẹ́ni Táyọ̀ Olúwatúyì tí gbogbo àwọn ènìyàn mọ̀ sí Tùkànà ló ti di olóògbé. Òwúrọ̀ òní