Wọ́n fẹ́ pa wá run Kí wọ́n ráàyè gba ilẹ̀ wa ni.Olúwa kò sì ní fún wọn ṣe…Caleb Muftwang
Gómìnà ìpínlẹ̀ Benue,Caleb Muftwang ti fẹ̀ṣùn kan àwọn Fúlàní darandaran tí wọ́n ń pa àwọn ènìyàn ipinlẹ̀ rẹ̀ bí ẹni […]
Gómìnà ìpínlẹ̀ Benue,Caleb Muftwang ti fẹ̀ṣùn kan àwọn Fúlàní darandaran tí wọ́n ń pa àwọn ènìyàn ipinlẹ̀ rẹ̀ bí ẹni […]
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ́yọ́ nígbà kan rí, Ọ̀mọ̀wé Victor Ọmọlolú Olúnlọ́yọ̀ọ́ ti tẹ́rí gbasọ.Àná ní bàbá àgbà náà kú lẹ́yìn ọdún
Olórí àjọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ tí a mọ̀ sí DSS ní ilẹ̀ wa Naijiria,Olúwatóṣìn Àjàyí ti pè fún òfin tí yóò máa
Ilé-iṣẹ́ Atúnrinrọ ti ó wà ní ìlú Àjàòkúta ní ìpínlẹ̀ Kogi ni ó ti ní Adarí tuntun.Ẹnu lọ́ọ́lọ́ọ́ yìí ni
Ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ ní ilẹ̀ Nàìjíríà ti yọ Julius Abure gẹ́gẹ́ bíi alága àpapọ ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party.
Ìgbìmọ̀ tó ń gbẹ́jọ́ awuyewuye tó ṣúyọ látàrí ètò ìdìbò sí ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Edo tó wáyé ní ọjọ́ kọkànlélógún
Gógó ni abúlé Láòṣò nítòsí Lájé ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Ìwọ̀ òòrùn Oǹdó kan níbẹ̀rẹ̀ ọ̀ṣẹ̀ yìí.Ohun tó mú ìkorò