Àgbàlagbà ni Ifeanyi Okowa àti Sheriff Oborevwori ,Wọ́n lẹ́tọ̀ọ́ lábẹ́ òfin láti dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ tó bá wù wọ́n…. Atiku
Ìgbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú PDP láàrin ọdún 1999 sí ọdún 2027, tíì tún ṣe olùdíje sí […]
Ìgbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú PDP láàrin ọdún 1999 sí ọdún 2027, tíì tún ṣe olùdíje sí […]
Ilẹ̀ Amẹrika ti sọ̀rọ̀ sókè tako gbogbo ìgbésẹ̀ ìjọba Donald Trump nípa síse ìwọ́de lọ́kan-ò-jọ̀kan káàkiri orílẹ̀-èdè náà.Wọ́n ní kò
Pòròpòrò ni omijé ń bọ́ lójú àwọn ènìyàn ní òpópónà Ìdànrè ní ìlú Àkúrẹ́ lọ́jọ́ ẹtì látàrí ìjàm̀bá ọkọ̀ àjàgbé
Ààrẹ Ọ̀nà Kakaǹfò ilẹ̀ Yorùbá,iba Gàni Adams ti sọ pé ọgbọ́n àti ète àtida ilẹ̀ Yorùbá rú ni òfin Ṣẹ̀ríà
Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà,Bọ́lá Tinúbú ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ tí yóò ṣe ọ̀fíntótó òhun ìwádìí tó múná dóko lórí ọ̀nà àátọ̀
Òní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹrin ọdún 2025 ló pé ogójì ọdún tí Bísọ́ọ̀bù ilẹ̀ Àkúrẹ́ tii tún ṣe Bíṣọ́ọ̀bù Aláṣẹ
Àwọn ará ìlú Ìgbàrà-òkè tíì ṣe olú ìlú ìjọba ìbílẹ̀ Ìfẹ́dọ̀rẹ́ ní ìpínlẹ̀ Oǹdó tú jáde sí àwọn òpópónà tó
Ìlúmọ̀ọ́ká onítíátà tó dá abúlé eré ìtàgé aládàáni sílẹ̀ ní Nàìjíríà nnì, Ibrahim Chatta ti ṣe ohun kàyééfì ńlá ní