Àìṣedédé Àwọn Mínísítà ló fa Ìyọnípò Wọn…Ọnànúgà
Bí Nnkan kò bá ṣe Àjànàkú,a kìí déédé rí awọ Erin lórí àtẹ̀,Òwe yìí ló dífá fún ìyọnípò àwọn Mínísítà […]
Bí Nnkan kò bá ṣe Àjànàkú,a kìí déédé rí awọ Erin lórí àtẹ̀,Òwe yìí ló dífá fún ìyọnípò àwọn Mínísítà […]
Ohaneye,Mamman àtàwọ́n mẹ́ta mìíràn lọ Bianca Ojukwu,Yuwatda àtàwọn marun-un mìíràn wole Láti fòpin sí awuyewuye tó ti ń jà ràn-ìn-ràn-ìn nílẹ̀
Ìjọba ìpínlẹ̀ Oǹdó ti ṣe àmúṣẹ ìlérí rẹ láti ríi dájú pé ayé túbọ̀ dẹndẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ ijoba ipinle
Ètò ìdìbò sí ipò Alága ìjọba ìbílẹ̀ àti àwọn kánsílọ̀ ló ti wáyé yíká ipinle Rivers loni-in. Bí-ó-tilẹ̀-jẹ́-pé ìdájọ́ ilé
Gómìnà ìpínlẹ̀ Edo, Godwin Obaseki àti ìyàwó rẹ̀ ti fi orile-ede Naijiria sílẹ̀ lọ sí orílẹ̀-èdè Venice. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ awuyewuye ló
Àjọ eleto idibo nipinle Ondo tí a mọ̀ sí ODIEC ti bèrè itanijí ohun ìlánilọ́yẹ̀ fún àwọn olóṣèlú ní ìgbáradì
Olùkọ́ àgbà Yunifásítì kan, tíí tún ṣe Olórí ẹ̀ka tó ń kọ́ni ní ìmọ̀ nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú nílé ẹ̀kọ́ gíga
Àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ Edo ti dìbò yan Gómìnà tuntun ti yóò máa ṣe àkóṣo ipinle náà fún ọdún mẹ́rin miiran.Onítọ̀hún