Ní ìpínlẹ̀ Rivers: Ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ fún àwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ ní ìwé Gbélé ẹ
Ní òjijì ni jàgínníyòdò àwa la wà ní ìjọba awọn alága ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Rivers di ìbànújẹ nígbà tí […]
Ní òjijì ni jàgínníyòdò àwa la wà ní ìjọba awọn alága ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Rivers di ìbànújẹ nígbà tí […]
Akọ̀wé ìjọba ìpínlẹ̀ àti gbogbo àwọn Kọmísánnà ni wọ́n gba ìwé Gbélé ẹ Gómìnà ìpínlẹ̀ Nasarawa, Abdullah Sule ti fún
Gómìnà ìpínlẹ̀ Rivers àná tíì tún í ṣe Mínísítà fún olú-ìlú ilẹ̀ wa,Nyensom Wike ti ṣe àpèjúwe Gómìnà tẹ́lẹ̀ rí
Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó tó tún ṣẹ̀ṣẹ̀ jàwé Olúborí nínú ìdìbò sí ipò Gómìnà tó wáyé ni ìpínlẹ̀ Oǹdó lọ́jọ́ kẹtàdinlogun
Igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó,Ọláyídé Adélàmí ti jẹ́wọ́ ọmọ ọkọ ní yúníìtì ibi tó ti dìbò ní bó ti fẹ̀yìn olùdíje
Igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó,Ọláyídé Adélàmí ti pàrọwà fún àwọn ènìyàn ipinlẹ̀ Oǹdó lápapọ̀ pàápàá jùlọ àwọn ènìyàn Ọ̀wọ̀ ati agbègbè
Ààrẹ ilẹ̀ America àná tíi tún ṣe olùdíje sí ipò Ààrẹ, Ọ̀gbẹ́ni Donald Trump ti jáwé Olúborí nínú ètò ìdìbò
Gómìnà tuntun tí àwọn ènìyàn ipinlẹ̀ Edo ṣẹ̀ṣẹ̀ dìbò yàn, Ọ̀gbẹ́ni Okpebolo ti sọ pé pèlú bí ariwo,ìjà,jàádì òhun làkáádí