Kò ṣéèwọ̀ nínú kíkí tí Mo lọ Kí Buhari…Atiku
Ìgbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí tii tún ṣe olùdíje sí ipò Ààrẹ lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú PDP nínú ètò […]
Ìgbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ rí tii tún ṣe olùdíje sí ipò Ààrẹ lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú PDP nínú ètò […]
Alága àwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Oǹdó, Họnọrébù Gbénga Fáṣúà ti kìlọ̀ fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ìdàgbàsókè agbègbè
Ògbóhùntarìgì Olóṣèlú kan tó tún jẹ́ ìtalẹ̀mú nínú ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Họnọrèbù Wálé Ọ̀kẹ́ ti fi ẹgbẹ́ Òṣèlú
Bí ọ̀rọ̀ tó ti ẹnu alága APC ní ilẹ̀ Nàìjíríà tíí tún ṣe gómìnà àná ní ìpínlẹ̀ Kano, Dókítà Abdullahi
Ògbóhuntarìgì Olóṣèlú kan tó ti fìgbà kan rí jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asojú-ṣòfin , Họnọrèbù Nicholas Ukachukwu ló jáwé olúborí
Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party nílẹ̀ wa Nàìjíríà ti fẹ̀ṣùn kan Olùdíje fún ipò Ààrẹ lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú
Èèkàn nínú olóṣèlú kan tó tí fìgbà kan rí díje fún ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú PDP
Ìgbìmọ̀ tó ń gbẹ́jọ́ awuyewuye tó ṣúyọ látàrí ètò ìdìbò sí ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Edo tó wáyé ní ọjọ́ kọkànlélógún
Bí ẹ̀ṣùn tí ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Rivers fi kan Adájọ́ àgbà ní ìpínlẹ̀ náà pé ó yí ọjọ́ oríire rẹ̀