Ọkọ̀ Pa Ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ènìyàn níbi Ọdún Ìbílẹ̀ kan ni Vancouver Fillipino
Lójijì ni ìdùnnú òhun ayọ̀ sáré di ìbànújẹ níbi ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ kan ni Vancouver Fillipino lálẹ́ àná Sátidé nígbà […]
Lójijì ni ìdùnnú òhun ayọ̀ sáré di ìbànújẹ níbi ayẹyẹ ọdún ìbílẹ̀ kan ni Vancouver Fillipino lálẹ́ àná Sátidé nígbà […]
Ọjọ́ burúkú èṣù gbomi mu ni ọjọ́ jímọ̀ ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹrin ọdún yìí jẹ́ fún àwọn ènìyàn ìdílé Alálàádé
Làlúrí burúkú ló ṣẹlẹ̀ lálẹ́ ọjọ́ ìṣẹ́gun ọ̀sẹ̀ yìí ní Santo Domingo ní orílẹ̀-èdè Dominican níbi tí àjà ilé fàájì
……ìfẹ̀hónú hàn gbòdé ní Àkúrẹ́……Wọ́n gbé òkú àwọn tí wọ́n pa lọ sí ẹnu ọ̀nà ọọ́fíìsì Gómìnà Ìbànújẹ dórí àgbà
Òjò àrọ̀ìrọ̀dá kan tó ti lọ́jọ́ ọdún ìtúnu àwẹ̀ tó kọjá yìí ti sọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn dì aláìnílé lórí mọ
Àwọn Ajínigbé ti gbé àlùfáà ìjọ Àgùdà kan ní Ejemekwuru, ni agbègbè ìjọba Ìbílẹ̀ Oguta, ní ìpínlẹ̀ Imo.Onitọ̀hún ni Àlùfáà
Kò dín ní ọmọ ilé Kéú Mẹ́tàdínlógún tó jẹ́ Ọlọ́run nípè láìròtẹ́lẹ̀ nínú ìjàm̀bá iná tó sọ ilé ẹ̀kọ́ kéú
Ìjàm̀bá iná àjóòkú kan tó ṣẹlẹ̀ lóru àná mọ́jú òní tí gba aṣọ lára ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn oníṣòwò inú ọjà náà