Èèmọ̀ Wọ̀lú o! Wòlíì Obìnrin gba ọkọ ọmọ ìjọ rẹ̀.Ó ní Olúwa ló ní kí òun ṣe bẹ́ẹ̀.
Arábìnrin ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ ìyáàfin Njokwu ló ti ké gbàjarè lọ sórí ètò orí […]
Arábìnrin ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ ìyáàfin Njokwu ló ti ké gbàjarè lọ sórí ètò orí […]
Àlùfáà Àgbà ìjọ Anglican kan ní Dáósísì Àkúrẹ́, Àlùfáà (Dókítà) Fágbèmí ti rọ àwọn Onígbàgbọ káàkiri àgbáyé láti ta kété