Ní Oǹdó,Ọmọ́tọ́lá dèròo Kóòtù nitori pé ó ba mọ́tò onímọ́tò jẹ́.
Ọkùnrin ẹni ọdún márùndínláàádọ́ta(45yrs) kan,Ọmọ́tọ́lá Ọlálékan ló ti ń jó lamba níwájú òfin ní Kóòtù Májísìréètì ti ìlú Òdìgbó ní […]
Ọkùnrin ẹni ọdún márùndínláàádọ́ta(45yrs) kan,Ọmọ́tọ́lá Ọlálékan ló ti ń jó lamba níwájú òfin ní Kóòtù Májísìréètì ti ìlú Òdìgbó ní […]
Abilékọ ẹni ọdún mẹ́rìnlèlógún kan, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Racheal tó fi ìlú Asaba ní ìpínlẹ̀ Delta ṣe ibùjókòó
ilé iṣẹ́ ọlọ́pàá ipinlẹ Enugu ti fi páḿpẹ́ òfin gbé òjòwúkùnrin kan Sunday Echege ,ẹni ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n tó ń gbé
Bí àlá ló ṣe rí nílé ìjọsìn ìjọ Mímọ́ Kristi láti Ọ̀run wá ìyẹn ,Celestial Church of Christ,Testimony Parish,Elerumoke,Ẹgbẹ́dá, Ìyànà
Àwọn Ọkùnrin Amòòkùnsèkà Méjì kan, Abubakar Ibrahim àti Isah Ayuba ti ń ṣẹ́jú pàkò bíi Mọ́námọ́ná látìmọ́lé látàrí bí wọ́n
Inú ìbànújẹ ni àwọn ènìyàn ipinlẹ̀ Oǹdó pàápàá jùlọ àwọn ará Anglican Grammar School,Ìkàrẹ́-Àkókó wà látàrí bíi ọmọbinrin kan tó
Ààrẹ ilẹ̀ yii, Asíwájú Bọ́lá Tinúbú tí jàwé akìwọwọ fún àwọn Ajínigbé Boko-haram àti Àṣẹ̀rùbàlú Bándíìtì kí wọ́n so ewé