Ní Òdìgbó;Pásítọ̀ fún Abirùn ọmọ Ọdún Mẹ́tàlàá lóyún
Kàyéfì ńlá ló jẹ́ fún àwọn ènìyàn ìlú Òkè Ìgbúròwò ní ìjọba ìbílẹ̀ Òdìgbò nígbà tí àríyànjiyàn sọ lórí ẹni […]
Kàyéfì ńlá ló jẹ́ fún àwọn ènìyàn ìlú Òkè Ìgbúròwò ní ìjọba ìbílẹ̀ Òdìgbò nígbà tí àríyànjiyàn sọ lórí ẹni […]
Adájọ́ Odùmóṣù tí ilé ẹjọ́ Májísìréètì tó wà ní Àgọ́ Òkò ní Abẹ́òkúta ti fi kobíowú wọn ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́ta
Ọwọ́ pálábá àwọn Amòòkùnsìkà ẹ̀dá tí wọn yan iṣẹ́ òkú wíwú àti ẹ̀yà ara ènìyàn títà láàyò ti ṣégi ní
Bí ẹní lu bàrà ní àwọn olùkọ mélòó kan ní ilé ẹ̀kọ́ Government Day Secondary School,Kúléndé, Ìlọrin ṣe lu Àgùnbánirọ̀
Kò jẹ́ tuntun mọ́ pé Ọkùnrin olókó kòmẹbí kan ní ilẹ̀ Equitorial Guinea, Bathaza Ebang Egonga bá irínwó obìnrin lò