Ìrìnàjò Ìkẹyìn Bàbá George bẹ̀rẹ̀ ní ilẹ̀ -Olújìí
Ìrìnàjò ìkẹyìn fún Diákónì Samson Òláníyì Adébáyọ̀ George ti bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ìṣìn ninu ijọ Oore-ọ̀fẹ́ Baptist Church, Ilẹ̀-Olújìí lánà-án Sunday. […]
Ìrìnàjò ìkẹyìn fún Diákónì Samson Òláníyì Adébáyọ̀ George ti bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ìṣìn ninu ijọ Oore-ọ̀fẹ́ Baptist Church, Ilẹ̀-Olújìí lánà-án Sunday. […]
Àlùfáà ìjọ Oore-ọ̀fẹ́ Baptist church,Ilẹ̀-Olújìí , Àlùfáà Philip Adékúnlé Ọmọ́kanyè ti rọ gbogbo ẹ̀dá alààyè láti máa ṣe àánú fún
Gbẹgẹdẹ gbiná níbi ìfọ̀rọ̀wérọ̀ ti ilé-iṣẹ́ Ìmóhùnmáwòrán Channel Tv ṣe fún àwọn olùdíje sí ipò Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́
Olórí ìjọ Ìràpadà Ọlọ́run lágbàáyé,(The Redeemed Christiana Church of God)Pásítọ̀ Adéjàre Adébóyè ti sọ lọ́jọ́ ẹtì tó kọjá lọ pé