Ẹni Rere Ní Èsù kìí ṣe Ẹni Burúkú… Àwọn Ọmọ Èṣù Lápapọ̀
Ó ti dájú gbangba pé àwọn ọmọlẹ́yìn Èṣù káàkiri àgbáyé ti kó ara wọn jọ láti ṣe ọdún Èṣù lápapọ̀ […]
Ó ti dájú gbangba pé àwọn ọmọlẹ́yìn Èṣù káàkiri àgbáyé ti kó ara wọn jọ láti ṣe ọdún Èṣù lápapọ̀ […]
Àjàfẹ́tọ̀ọ́ọmọnìyàn nnì, tíí tún ṣe Agbẹjọ́rò, Délé Fárótìmí ti gba ìdáǹdè láti ọ̀dọ̀ ilé ẹjọ́ Májísíréètì kan ní ìlú Adó-Èkìtì.
Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó, Họnọrébù Lucky Orímisàn Aiyédàtiwa ti lu awọn ọmọ olóógun ilẹ̀ Nàìjíríà lọ́gọ ẹnu fún ipa takuntakun ti
Ògbóǹtarìgì Oníwáàsí Àgbáyé Nnì, Muhideen Àjàní Bello ti di olóògbé.Ohun pàtó tó fa ikú olóògbé náà kò ti fi ojú
Adelé alága ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ Oǹdó, Ọ̀gbẹ́ni Adémọ́lá Ọlápàdé ti fi àwọn òṣìṣẹ́ ipinlẹ̀ Oǹdó lọ́kàn balẹ̀ pé
Alákóso fún ọ̀rọ̀ tó jẹ mọ́ àwọn obìnrin ní ìpínlè Oǹdó, Díákónì Lọlá Fágbèmí ti ṣe Ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ tó máa