Àṣejù Baba Àṣetẹ́;Ọba Olórílé ti Orílé-Ifọ̀ fi Ìwà Rádaràda Lé ara Rẹ̀ Lórí Ìtẹ
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn,Dàpọ̀ Abíọ́dún ti pàṣẹ kí Olórílé ti Orílé-Ifọ̀ ní ìjọba ìbílẹ̀ Ifọ̀ ní ìpínlẹ̀ ògùn,Ọba Sẹ̀míù Ògúnjọbí pé […]
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn,Dàpọ̀ Abíọ́dún ti pàṣẹ kí Olórílé ti Orílé-Ifọ̀ ní ìjọba ìbílẹ̀ Ifọ̀ ní ìpínlẹ̀ ògùn,Ọba Sẹ̀míù Ògúnjọbí pé […]
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun láàrin ọdún 1999 sí Ọdún 2003, tó ti tún fìgbà kan jẹ́ alága àkọ́kọ́ fún ẹgbẹ́ òṣèlú
Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó, Lucky Orímisàn Aiyédàtiwa ti sọ yanya pé ó di ọjọ́ kẹwàá oṣù kejì ọdún yìí kí wọ́n
Òǹkọrin eré Highlife kan ni ipinlẹ̀ Delta,Arube Otor ló ti gbára dì báyìí láti fẹ ìyàwó mêta ni ọjọ́ kan
ìjọba fowó kún owó oṣù Àwọn Òṣìṣẹ́ Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lábẹ́ ìsàkóso ààrẹ Bọ́lá Tinúbú fowó kún owó oṣù àwọn