Ojúṣe mi ni láti Sìn ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa… Andrew Ògúnṣakin
Alága ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa, Họnọrèbù Andrew Ògúnṣakin ti sọ pé ìdàgbàsókè ìjọba Ìbílẹ̀ Òkìtìpupa ló jẹ òun lógun.Ògúnṣakin ṣàlàyé ọ̀rọ̀ […]
Alága ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa, Họnọrèbù Andrew Ògúnṣakin ti sọ pé ìdàgbàsókè ìjọba Ìbílẹ̀ Òkìtìpupa ló jẹ òun lógun.Ògúnṣakin ṣàlàyé ọ̀rọ̀ […]
Aláàfin ìlú ọ̀yọ́,Ọba Akeem Abímbólá Ọ̀wọ́adé ti rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà lápapọ̀ láti gba àlàáfíà láàyè ní ọ̀nà wọn gbogbo.
Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé nílẹ̀ wa,Olúbùnmi Túnjí Òjó ti kéde ọjọ́ ajé ọjọ́ kìíní àti ọjọ́ ìṣẹ́gun ọjọ́ keji oṣù
Sẹ́nétọ̀ tó ń ṣojú ẹkùn ídìbò ààrin gbùngbùn Kogi ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà,Sẹ́nétọ̀ Natasha Akpoti Uduaghan ló ṣeéṣe kó
Ògbóhùtarìgì akọ̀ròyìn tó máa ń fi irun bójú fín àwọn Amòòkùnsìkà lápe ní ilẹ̀ Ghana nnì,Anes Aremeyaw ni ilé ẹjọ́
Ilẹ̀ Namibia ti yan Ààrẹ àkọ́kọ́ lóbìnrin.Onítọ̀hún ni Abilékọ Netumbo Nandi Ndaitwah tí àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ mọ̀ sí NNN.Ọmọ ẹgbẹ́
Láti inú oṣù Kejì tí òjòjò ti ń ṣògún Pápà mímọ́ jùlọ Fransisco ti ìjọ Àgùdà lágbàáyé,ọọ́fíìsì Alukoro àgbà fún
Alága ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa,Họnọrèbù Andrew Ògúnṣakin ti sàlàyé bí ìdàgbàsókè ìjọba Ìbílẹ̀ Òkìtìpupa ṣe jẹ ẹ́ lógún sí àti bó