Ìròyìn
Uzodinma kó àwọn Gómìnà Onítẹ̀síwájú ṣòdí lọ kí Buhari ní Kaduna.
Alága ágbáríjọ àwọn Gómìnà Onítẹ̀síwájú ti wọ́n gun ẹṣin ẹgbẹ́ òṣèlú APC dé orí àléfà tíì tún ṣe Gómìnà ìpínlẹ̀
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tẹ́lẹ̀, ọ̀mọ̀wé Victor Ọmọlolú Olúnlọ́yọ̀ ti Jẹ́ Ìpè Ẹlẹdàá
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ́yọ́ nígbà kan rí, Ọ̀mọ̀wé Victor Ọmọlolú Olúnlọ́yọ̀ọ́ ti tẹ́rí gbasọ.Àná ní bàbá àgbà náà kú lẹ́yìn ọdún
Àwọn Òṣìṣẹ́ Ààbò ilẹ̀ Nàìjíríà kò tó láti kojú ìpèníjà ètò àbò…. Àjàyí
Olórí àjọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ tí a mọ̀ sí DSS ní ilẹ̀ wa Naijiria,Olúwatóṣìn Àjàyí ti pè fún òfin tí yóò máa
Ilé-iṣẹ́ Atúnrinrọ Àjàòkúta ti ní Adarí tuntun
Ilé-iṣẹ́ Atúnrinrọ ti ó wà ní ìlú Àjàòkúta ní ìpínlẹ̀ Kogi ni ó ti ní Adarí tuntun.Ẹnu lọ́ọ́lọ́ọ́ yìí ni
Ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ yọ Abure bíi alága ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party
Ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ ní ilẹ̀ Nàìjíríà ti yọ Julius Abure gẹ́gẹ́ bíi alága àpapọ ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party.
Ẹgbẹ́ ANBROAD kí igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó kú oríire Ayẹyẹ Ọjọ́ ìbí rẹ̀
Ẹgbẹ́ Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí a mọ̀ sí ANBROAD , ẹ̀ka ti ìpínlẹ̀ Oǹdó ti kí igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó, Ọ̀gbẹ́ni
