Ní ìpínlẹ̀ Oǹdó, Ìṣẹ̀lẹ̀ Ìjínigbé ń peléke síi.
Wọ́n jí Tọ́pẹ́ gbé lỌ́wọ̀,wọ́n ní kí ẹbí rẹ̀ ó mú ogún mílíọ̀nù wá. Ará ìlú ń sá kíjokíjo. Ìṣẹ̀lẹ̀ […]
Wọ́n jí Tọ́pẹ́ gbé lỌ́wọ̀,wọ́n ní kí ẹbí rẹ̀ ó mú ogún mílíọ̀nù wá. Ará ìlú ń sá kíjokíjo. Ìṣẹ̀lẹ̀ […]
Lójijì ní ìròyìn tàn kiri ní kùtùkùtù òwúrò òní pé ògbóhùntarigì olóṣèlú nnì Doyin Òkúpè di olóògbé. Ó ti tó
Bí àwọn ọlọ́pàá tó gbé òkú ọ̀kan lára wọn, Blessing Yusuf Suleiman tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ọmọ Alhaja lọ
Ọ̀gágun àgbà Toheed Lágbájá Alágbà Tajudeen Lágbájá tíí ṣe àbúrò bàbá olórí ọmọ ogun ilè wa tó di olóògbé ,Ọ̀gágun
Olórí àwọn ọmọ olóógun orí -ilẹ̀ nílẹ̀ wa, Ọ̀gágun àgbà Taoreed Lágbájá tí di Olóògbé.Àtẹ̀jáde kan tó gba ẹnu Olùdámọ̀ràn
Hmmm! Ikú ti gbẹ̀mí ìyàwó Gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom, Arábìnrin Patience Umo Eno.Àná ọjọ́ ọjóbọ ni Arábìnrin ọ̀hún jẹ́ ìpè