Ẹgbẹ́ Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ANBROAD yóò ṣe ìpàdé loni-in
Ẹgbẹ́ Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí a mọ̀ sí ANBROAD ẹ̀ka ti ìpínlẹ̀ Oǹdó yóò ṣe ìpàdé wọn olóṣooṣù loni-in ní olú […]
Ẹgbẹ́ Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí a mọ̀ sí ANBROAD ẹ̀ka ti ìpínlẹ̀ Oǹdó yóò ṣe ìpàdé wọn olóṣooṣù loni-in ní olú […]
Ní ìpínlẹ̀ Oǹdó Àwọn èrò tó ń lọ sí Saudi Arabia láti ìpínlẹ̀ Oǹdó ti ṣetán báyìí nipasẹ ìgbáràdì ọlọ́kanòjọ̀kan.
Alága ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa, Họnọrèbù Andrew Ògúnṣakin ti fòfin de àwọn Sarin-sagolo ti a mọ̀ sí Scavengers ní ìjọba ìbílẹ̀
Kò ní yẹni títí kí ilẹ̀ má ṣe ṣú.Bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀ rí fún gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó, Lucky Orímisàn Aiyédàtiwa
Ìyàwó Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà,Sẹ́nétọ̀ Olúrẹ̀mí Tinúbú ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ètò Ìrètí ọ̀tun tòhún ti àtinúdá(Renew hope initiative). lónì-ín ní Gbọ̀ngàn
Ọ̀gá Ọlọ́pàá ipinlẹ Oǹdó, Ọ̀gbẹ́ni Wilfred Afọlábí ti pàṣẹ kí wọ́n gbé DPO Ìgbàrà-Òkè, Ọ̀gbẹ́ni Gàníyù Dáwódù kúrò ní ìlú
Ìjà ààlà ìlẹ̀ ti gbẹ̀mí ẹnìkan tí wọ́n sì tiná bọ odidi ilé mẹ́sàn-án ní Àágba ní ìjọba ìbílẹ̀ Sùúrùlérè
Gómìnà ìpínlẹ̀ Benue,Caleb Muftwang ti fẹ̀ṣùn kan àwọn Fúlàní darandaran tí wọ́n ń pa àwọn ènìyàn ipinlẹ̀ rẹ̀ bí ẹni