Ó ga ooo!Pọ́tébù rẹ́wọ̀n he
Gbajúgbajà Olórin ṣèwọ́ṣèwọ́ ti ẹnu kìí sìn lára rẹ̀ bíi Afọ́ìkéèmù nnì,Abeeb Òkìkíọlá tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Pọ́tébù ni […]
Gbajúgbajà Olórin ṣèwọ́ṣèwọ́ ti ẹnu kìí sìn lára rẹ̀ bíi Afọ́ìkéèmù nnì,Abeeb Òkìkíọlá tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Pọ́tébù ni […]
Igi ìwé,gbòǹgbò ìmọ̀ kan tíí tún ṣe ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ nípa ààtò ẹ̀kọ́ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga jùlọ Yunifásítì Adékúnlé Ajáṣin
Ìgbìmọ̀ Aṣàkóso ilé ẹ̀kọ́ gíga jùlọ Yunifásítì ìjọba Àpapọ̀ tó wà ní ìlú Ọyẹ́-Èkìtì ní ìpínlẹ̀ Èkìtì ti pàṣẹ fún
Àwọn Ìgbìmọ̀ Aláṣẹ ilé ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun tó wà ní ìlú Ìré ti ti ilé ìwé gíga náà pa.Ohun
Gómìnà ìpínlẹ̀ Oǹdó, Lucky Orímisàn Aiyédàtiwa ti yan Òṣemàwé ti ìlú Oǹdó, Ọba Dókítà Victor Kíladéjọ,Jílò Kẹta gẹ́gẹ́ bíi Olórí
Ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Ṣóyínká Pàràkòyí onimọ̀ iṣẹ́ ọnà àti Lítíréṣọ̀ nnì, Ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Ṣóyínká ti sọ pé ‘Pa á jẹ́,bà á