Amúlùúdùn
Obi Cubana! Bá mi gbé ìràwọ̀ mi tí o lò,Kí o sì wá gbé ọmọ rẹ oo! …Helen Ati
Ọmọ ilẹ̀ Kenya tii ṣe ọ̀kan lára àwọn àlè tó bímọ fún gbajúgbajà olówó Aríayẹyẹ yiọ̀ nnì,Pascal Okechukwu,tí gbogbo ènìyàn
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Ṣetán láti ran KAP lọ́wọ́…Mákindé
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ́yọ́,Onímọ̀ ẹ̀rọ Ṣèyí Mákindé ti jẹ́jẹ̀ẹ́ àtìlẹ́yìn tó gbọ́nngbọ́n fún ilé iṣẹ́ KAP FILM VILLAGE AND RESORTS tó
Mo ṣetán láti ṣe ìyàwó Kẹfà…Tókè Mákinwá
Ògbóhùntarìgì oníṣẹ́ orí afẹ́fẹ́ kan, Omidan Tókèr Mákinwá ti sàlàyé pé òun kò kọ àjẹkù níbi tí òun bá ọ̀rọ̀
Ibrahim Chatta fi ẹṣin ta Aláàfin lọ́rẹ
Ìlúmọ̀ọ́ká onítíátà tó dá abúlé eré ìtàgé aládàáni sílẹ̀ ní Nàìjíríà nnì, Ibrahim Chatta ti ṣe ohun kàyééfì ńlá ní
Nítorí ìlú tó le; Owó Oṣù Mẹ́rin ni mo jẹ àwọn Òṣìṣẹ́ Mejilélógójì (42) tí mo ní… Ibrahim Chatta
Gbajúgbajà òṣìṣẹ́ tíátà tó ní ẹ̀bùn àìmọye nnì, Ibrahim Chatta ti lahùn síta láìfòlò fọhùn pé lóòótọ́ ni ìlú le
Adéwálé Àyúbà Pé ẹni Ọgọ́ta Ọdún láyé: Tinúbú kí i kú oríire
Èèkàn Olórin fújì nnì tíì tún ṣe ọba orin fújì Bọ̀ǹsúè ló ti pé ọgọ́ta ọdún lókè erùpẹ̀.Ogunlọ́gọ̀ àwọn ènìyàn
Alukoro Ẹgbẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ANBROAD;Kẹ̀kẹ́ Àwàdà Gba Àmì Ẹ̀yẹ
Ògbóhùntarìgì Afèdèsẹṣọ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ nnì, tí àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ mọ̀ si Kẹ̀kẹ́àwàdà, Ọ̀gbẹ́ni Adékúnlé Adéwùmí tíí ṣe Olùdarí ilé iṣẹ́ kẹké Àwàdà
Ẹgbẹ́ ANBROAD sí Ọọ́fíìsì tuntun ní ìpínlẹ̀ Oǹdó.
Ẹgbẹ́ Akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ní Nàìjíríà tí a mọ̀ sí ANBROAD, ẹ̀ka ti ìpínlẹ̀ Oǹdó ti ṣí ọọ́fíìsì titun.Ojúlé Kẹrìnléláàádọ́ta, agbègbè
