Nítorí ọ̀rọ̀ ìbálòpọ̀;Ìgbìmọ̀ Aṣàkóso FUOYE ní kí Gííwá ó máa relé
Ìgbìmọ̀ Aṣàkóso ilé ẹ̀kọ́ gíga jùlọ Yunifásítì ìjọba Àpapọ̀ tó wà ní ìlú Ọyẹ́-Èkìtì ní ìpínlẹ̀ Èkìtì ti pàṣẹ fún […]
Ìgbìmọ̀ Aṣàkóso ilé ẹ̀kọ́ gíga jùlọ Yunifásítì ìjọba Àpapọ̀ tó wà ní ìlú Ọyẹ́-Èkìtì ní ìpínlẹ̀ Èkìtì ti pàṣẹ fún […]
Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ́yọ́,Onímọ̀ ẹ̀rọ Ṣèyí Mákindé ti jẹ́jẹ̀ẹ́ àtìlẹ́yìn tó gbọ́nngbọ́n fún ilé iṣẹ́ KAP FILM VILLAGE AND RESORTS tó
Òní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹrin ọdún 2025 ló pé ogójì ọdún tí Bísọ́ọ̀bù ilẹ̀ Àkúrẹ́ tii tún ṣe Bíṣọ́ọ̀bù Aláṣẹ
Ògbóhùntarìgì oníṣẹ́ orí afẹ́fẹ́ kan, Omidan Tókèr Mákinwá ti sàlàyé pé òun kò kọ àjẹkù níbi tí òun bá ọ̀rọ̀
Ọ̀gá Ọlọ́pàá ipinlẹ Oǹdó, Ọ̀gbẹ́ni Wilfred Afọlábí ti pàṣẹ kí wọ́n gbé DPO Ìgbàrà-Òkè, Ọ̀gbẹ́ni Gàníyù Dáwódù kúrò ní ìlú
Akọ́nimọ̀ọ́gbá ẹgbẹ́ Agbábọ́ọ̀lù Super Eagles tẹ́lẹ̀, Christian Chukwu ti di olóògbé ní ẹni ọdún merinléláàádọ́rin (74 yrs) Òwúrọ̀ àná ni
Àwọn ará ìlú Ìgbàrà-òkè tíì ṣe olú ìlú ìjọba ìbílẹ̀ Ìfẹ́dọ̀rẹ́ ní ìpínlẹ̀ Oǹdó tú jáde sí àwọn òpópónà tó
Ìlúmọ̀ọ́ká onítíátà tó dá abúlé eré ìtàgé aládàáni sílẹ̀ ní Nàìjíríà nnì, Ibrahim Chatta ti ṣe ohun kàyééfì ńlá ní