Ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun,Oyin ta Àgbẹ̀ kan pa nínú oko rẹ̀.
Ọjọ́ burúkú èṣù gbomi mu ni ọjọ́ jímọ̀ ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹrin ọdún yìí jẹ́ fún àwọn ènìyàn ìdílé Alálàádé […]
Ọjọ́ burúkú èṣù gbomi mu ni ọjọ́ jímọ̀ ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹrin ọdún yìí jẹ́ fún àwọn ènìyàn ìdílé Alálàádé […]
Pòròpòrò ni omijé ń bọ́ lójú àwọn ènìyàn ní òpópónà Ìdànrè ní ìlú Àkúrẹ́ lọ́jọ́ ẹtì látàrí ìjàm̀bá ọkọ̀ àjàgbé
Ààrẹ Ọ̀nà Kakaǹfò ilẹ̀ Yorùbá,iba Gàni Adams ti sọ pé ọgbọ́n àti ète àtida ilẹ̀ Yorùbá rú ni òfin Ṣẹ̀ríà
Igi ìwé,gbòǹgbò ìmọ̀ kan tíí tún ṣe ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ nípa ààtò ẹ̀kọ́ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga jùlọ Yunifásítì Adékúnlé Ajáṣin
Ọkùnrin ẹni ọdún márùndínláàádọ́ta(45yrs) kan,Ọmọ́tọ́lá Ọlálékan ló ti ń jó lamba níwájú òfin ní Kóòtù Májísìréètì ti ìlú Òdìgbó ní
Ìyàwó Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà,Sẹ́nétọ̀ Olúrẹ̀mí Tinúbú ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ètò Ìrètí ọ̀tun tòhún ti àtinúdá(Renew hope initiative). lónì-ín ní Gbọ̀ngàn
Ọmọ ilẹ̀ Kenya tii ṣe ọ̀kan lára àwọn àlè tó bímọ fún gbajúgbajà olówó Aríayẹyẹ yiọ̀ nnì,Pascal Okechukwu,tí gbogbo ènìyàn
Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà,Bọ́lá Tinúbú ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ ìgbìmọ̀ tí yóò ṣe ọ̀fíntótó òhun ìwádìí tó múná dóko lórí ọ̀nà àátọ̀
Bí ọ̀rọ̀ tó ti ẹnu alága APC ní ilẹ̀ Nàìjíríà tíí tún ṣe gómìnà àná ní ìpínlẹ̀ Kano, Dókítà Abdullahi