Ikú pa Doyin Òkúpè:Ìpẹ́ru Mì tìtì
Lójijì ní ìròyìn tàn kiri ní kùtùkùtù òwúrò òní pé ògbóhùntarigì olóṣèlú nnì Doyin Òkúpè di olóògbé. Ó ti tó
Ìdàgbàsókè ìjọba Ìbílẹ̀ Òkìtìpupa ló jẹ mí lógún..Ọ̀gúnṣakin
Alága ìjọba ìbílẹ̀ Òkìtìpupa,Họnọrèbù Andrew Ògúnṣakin ti sàlàyé bí ìdàgbàsókè ìjọba Ìbílẹ̀ Òkìtìpupa ṣe jẹ ẹ́ lógún sí àti bó
Ní ìpínlẹ̀ Rivers: Ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ fún àwọn alága ìjọba ìbílẹ̀ ní ìwé Gbélé ẹ
Ní òjijì ni jàgínníyòdò àwa la wà ní ìjọba awọn alága ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Rivers di ìbànújẹ nígbà tí
Mi ò gbà kí Akpabio bá mí sùn ló ṣe ń bínú Mi… Natasha
Sẹ́nétọ̀ tó ń ṣojú ẹkùn ìdìbò ààringbùngbùn Kogi nílé ìgbìmọ̀ Aṣòfin àgbà ní Abuja,Amòfin Natasha Akpoti Uduaghan tí fẹ̀sùn kan
Ẹ jọ̀wọ́, Níbo ni Àjọ Road Safety Wà o?
Bí ènìyàn bá rí bí àwọn ọkọ̀ ṣe ń di ẹrù ní ìdìkudì ní ọ̀nà Òkìtipupa sí Ọ̀rẹ̀, àánú ọkọ̀,ọlọ́kọ̀,ọ̀nà
Ṣé ìdíje Omidan Rèé tabi ti Aṣẹ́wó?
Oyewumi OyedotunOyè Oyèdọ̀tun jẹ́ gbajúgbajà Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Oníròyìn,Akéwì,Olórin,Ọ̀ǹkọ̀wé, àti Ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn.Ìfẹ́ rẹ̀ sí iṣẹ́ ìròyìn àti èdè Yorùbá ló fa ìdásílẹ̀
