Àjọ EFCC lágbára láti fínro Ma éniyòówù tó bá pa owó ìlú Ní Póńpó….. Ilé ẹjọ́ tí ó ga jù lọ nilẹ̀ wa.

Ilé ẹjọ́ tí ó ga jù lọ tí a mọ̀ sí Supreme Court ti fi ọwọ́ òsi da ẹjọ́ tí àwọn ìjọba ìpínlẹ̀ nilé wa pe tako agbára àjọ EFCC láti fi páńpẹ́ ọba gbé ẹni yòówù tó bá pa owó ìlú ní Póńpó.

Nígbà tí ó ń gbé ẹjọ kalẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ náà, Adájọ́ Uwani Abba Aji tí ó léwáju àwọn adájọ́ yòókù ní ẹjọ́ náà kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ rárá.Ó wá fi ọwọ́ méjèèjì dà á nù.Agbẹjọ́rò àgbà ní ìpínlẹ̀ Kogi ló pe agbẹjọ́rò àgbà nile wa lẹ́jọ́ lórí ọ̀rọ̀ náà.

Ìjọba Olóyè Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ ló dá àjọ EFCC,ICPC àtàwon  bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ silẹ nígbà tó wà lórí àlèéfà.

1 thought on “Àjọ EFCC lágbára láti fínro Ma éniyòówù tó bá pa owó ìlú Ní Póńpó….. Ilé ẹjọ́ tí ó ga jù lọ nilẹ̀ wa.”

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top
×