
Ààrẹ Bọ́lá Tinúbú ti yan ẹni to ti fìgbà kan rí jẹ́ Ààrẹ àwọn Ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ni ilé ìwé gíga jùlọ Yunifásítì nilẹ̀ wa, òun kan náà tún ni alága àjọ elétò ìdìbò àná nílé wa, Ọ̀jọ̀gbọ́n Atahiru Jega gẹ́gẹ́ bí Olùbádámọ̀ràn pàtàkì lórí ohun ọ̀ṣìn.
Lẹ́yẹ-ò-sòkà ni ìyànsípò náà ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́.

Oyè Oyèdọ̀tun jẹ́ gbajúgbajà Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Oníròyìn,Akéwì,Olórin,Ọ̀ǹkọ̀wé, àti Ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn.Ìfẹ́ rẹ̀ sí iṣẹ́ ìròyìn àti èdè Yorùbá ló fa ìdásílẹ̀ ìkànnì yìí.A ti fi ìkòkò ṣe ọbẹ̀,ó yá ẹ je ká tọ́ ọ wò..Oyinmọmọ!
