Àjọ Àgbáyé USAID ló Ń Ṣe Onígbọ̀wọ́ Àwọn Aṣẹ̀rùbàlú bíi Boko Haram,Alqueda,abbl….Scott Perry

Ìwọ lò ń ṣe mí,ìwọ lò ń gbà mí, báwo la ṣe ń dúpẹ́ lọ́wọ́ ẹni tó ń ṣeni tó tún ń gbani?Ṣé ká má purọ́ tan ara wa jẹ,láìfàbòsí sọ igbá àlapà di igbá lúúrú; ọtá gedegbe ni awọn òyìnbó jẹ́ sí wa ní ilẹ̀ Adúláwọ̀.

Etí mélòó ló ń gbọ́ pé àwọn àjọ USAID ń ná owó tó lórúko láti ṣe onígbọ̀wọ́ fún awọn Al-qaeda,Boko haram àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àjọ Àṣẹ̀rùbàlú mìíràn?

Ọ̀kan lára àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin aṣòfin ilẹ Amẹ́ríkà, Scot Perry ló fojú òrò yìí léde pẹ̀lú ẹ̀ri tó dájú.Koda, ó fi ẹ̀ṣùn kan àwọn ìjọba tó ti kojá ní ilẹ Amẹ́ríkà

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top
×