Iná Àjóòkù ti fẹ́rẹ̀ Pa Amerika Run ooo!

Iná Àjóòkù kan tó ń fò sókè bí ẹyẹ ti fẹ́rẹ̀ jó ìlú Amerika run oo. Iná tó bẹ̀rẹ̀ ní California ló ti ń tán káàkiri ì àwọn ìlú ńláńlá ní orílẹ̀-èdè náà.

Gbogbo akitiyan àti ipá àwọn àjo Panápaná láti rẹ́yìn iná ọ̀hún ló já sí pàbó.Ẹgbàágbèje ọkọ̀ òfurufú Abàníbi-ó-wù-ú ló ń fò káàkiri láti pa iná náà

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top
×