Èèmọ̀ Wọ̀lú oo! Ìyàwó fi Májèlé Sínú Oúnjẹ fún Ọkọ Àti Àwọn Àlejò Lójọ́ Ìgbéyàwó Wọn Ní Ìpínlẹ̀ Zamfara

Ìyàwó àṣẹ̀ṣẹ̀gbé kan tí wọn kò tíì fi orúkọ rẹ̀ léde wà nibi tó ti ń ṣẹ́jú pàkò ní akóló àjọ ọlọ́pàá ipinlẹ Zamfara bayii lori èṣùn pé fi Májèlé Sínú Oúnjẹ àwọn  àlejò tó wá sí ibi patí ìgbéyàwó wọn.Kódà,ẹlẹ́kọ ọ̀run polówó fún ọ̀kan lára àwọn àlejò ọ̀hún tí ọkọ ìyàwó fúnra rẹ̀ si wá ní ẹsẹ̀ kan ayé,ẹsẹ̀ kan ọ̀run.

Alukoro àjọ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ naa,Saii’lsu Adam ló fi ojú ọ̀rọ̀ yìí léde ní ìlú Guzau nígbà tó ń bá àwọn oníròyìn fọ̀rọ̀ jẹ̀wọ̀.

Adam ni ìyàwó àti àwọn ẹlẹ́gbẹ́rò rẹ̀ ni wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ láti ṣe ṣûtá náà.Ó wá tẹ̀ síwájú pé àjọ Ọlọ́pàá kò ní ainm

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top
×