Nítorí Iṣu, Joshua Lu Ìyàwó Rẹ̀ Pa Ní Ìpínlẹ̀ Ebonyi

Charity Joshua

Ọkùnrin ẹní ogójì ọdún kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Joshua ní ó ti lu ìyàwó rẹ̀,Charity pa láìpẹ́ yìí ni  Nsokkar, ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Ezza ní ìpínlẹ̀ Ebonyi.

Ìròyìn tó tẹ̀ wá lọ́wọ́ ṣàlàyé pé Joshua pàṣẹ pé iṣu ni kí ìyàwó òun ṣè gégé bíi oúnjẹ alẹ́ ṣugbọn iyawo ní iṣu díndín ni òun fi;tí ó sì tako àṣẹ ọkọ rẹ̀ láti dín iṣu.

Bayii ni ìbínú ṣe ríu bò ó lójú tó bẹ́ẹ̀ tó fi lu ìyàwó rẹ̀ títí tí ẹ̀mí fi bọ́ ní ara rẹ̀.

Joshua ti wà ní akóló awọn ọlọ́pàá ní olú ìlú ìpínlẹ̀ náà nígbà tí ìwádìí ń tẹ̀ síwájú lórí ọ̀rọ̀ náà

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top
×