Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ọmọ Ẹgbẹ́ NULGE ní ìpínlẹ̀ Oǹdó wú mi Lórí…Akínrìnlọ́lá

Ààrẹ ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Oǹdó ti a mọ̀ sí NULGE,Comrade Frederick Gbénga Akínrìnlọ́lá ti lu àwọn ọmọ ẹgbẹ́ náà lọ́gọ ẹnu fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ láàrin àwọn ọmọ ẹgbẹ́ eléyìí tó mú ìdàgbàsókè tí kò lẹ́gbẹ́ bá ẹgbẹ́ náà ní ìjọba ìbílẹ̀ kóówá wọn àti ipinlẹ Oǹdó lápapọ̀.

Akínrìnlọ́lá fojú ọ̀rọ̀ yìí lóde

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top
×