

Bí-ó- tilẹ̀-jẹ́-pé àjọ INEC kò tíì sọ ẹni tó wọlé yanya ninu ètò ìdìbò sí ipò Gómìnà ìpínlẹ̀ Edo, ṣùgbọ́n òǹkà tó wà nílẹ̀ bayii ti fi hàn pé Oludije lábẹ́ àsìá ẹgbẹ́ òṣèlú APC ló sì ń mókè.
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn ń bi láìpẹ́

Oyè Oyèdọ̀tun jẹ́ gbajúgbajà Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ Oníròyìn,Akéwì,Olórin,Ọ̀ǹkọ̀wé, àti Ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn.Ìfẹ́ rẹ̀ sí iṣẹ́ ìròyìn àti èdè Yorùbá ló fa ìdásílẹ̀ ìkànnì yìí.A ti fi ìkòkò ṣe ọbẹ̀,ó yá ẹ je ká tọ́ ọ wò..Oyinmọmọ!
