L’Óǹdó, Àwọn Ajínigbé fi ọta ìbọn Wẹ ọkọ̀ Akérò GUO tó ń lọ Sí Abuja

Bí ìgbà tí àrá ń sán ni ìbọn ṣe ń dún lára ọkọ̀ èro GUO tó ń lọ sí Abuja ní ọjọ ìṣẹ́gun àná láàrin Àkùnù sí Àyèrẹ́ ni ìpínlè Kogi.

Óṣojúmipàtó tó fí ìṣẹ̀lẹ̀ náà léde lórí ẹ̀rọ Abẹ́yẹfò twitter rẹ̀.Gẹ́gẹ́ bó ti wí, ní kété tí mọ́tò náà kúrò ní ọ̀dọ̀ àwọn ọlọ́pàá ni wọ́n ń ṣàdédé gbọ́ ìró ìbon lọ́tùn-lósì tó bẹ́ẹ̀ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ sì fara pa yánnayànna.ṣùgbọ́n wọn kò jí ẹnikẹni gbé.

Gbogbo ìgbà ni ìṣẹ̀lẹ̀ ìjínigbé máa ń wáyé ní ọ̀gangan ibi ti ìṣẹ̀lẹ̀ yìí tí sí.

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Scroll to Top
×